Read Microsoft Word - haruna ishola text version

E ba wa dele

E mo nipa wa

E polowo oja yin

AKEDE Agbaye

Idanileko ALAROYE

Bi o ba fe ba wa sise

Adiresi wa

Itan igbesi aye Haruna Isola, oga awon alapala patapata

Olayiwola Alaga

Awon Iroyin to se koko O sele! Kunle lu magun

IBA sôe pe woôn n koôrin joôba, a ba fun Isôoôla lade,

Iba sôe pe woôn n koôrin joôba, a ba fun Isôoôla lade. A ba fun Isôoôla lade nitori ede to mu waye, a ba fun Isôoôla lade nitori ede to mu waye, Iba sôe pe woôn n koôrin joôba, a ba fun Isôoôla lade. Haruna Isôoôla lo koôrin beôeô. Haruna Isôoôla niyeôn, oômoô Beeribelo, n'Ijeôbu-Igbo. Haruna Isôoôla, Baba Gani Agba. Sôugboôn bi a ko tieô wi, bi a ko tieô soô, boun naa ko tileô fi koôrin, atoômoôde ilu atagba ilu, ta ni yoo pe Baba Gani ki i sô'oôba akoôrin. Oôba nla ni, oôba to ju oôba loô, baba awoôn oôba ni, nile orin. Ohun teeyan kan ba moô i sôe, ko sôe e daadaa o. Ko sôe e daadaa, nitori oni koô, nitori oôjoô mi-in ni. Ninu osôu koôkanla, oôdun yii, ni yoo di oôdun Haruna Ishola moôkandinloôgboôn t'Alaaji Haruna Isôoôla ti ku, sôugboôn loju awoôn mi-in, bii pe ana yii lo ku ni. Sôe ojoojumoô ni woôn n gboô orin reô, atoôba atijoye ileô Yoruba, beeyan dele woôn yoo ba orin Haruna pade laafin woôn. Oôkan ninu awoôn to sôoriire juloô nidii isôeô orin n'Isôoôla oômoô A-nsôeni-lode-ko-to-tile, orin lo koô to feôyawo, orin lo koô to bimoô, ko si si iru nnkan ti woôn gun nileô yii ti Haruna ko gun, beôeô loôpoô ilu oyinbo to de, pupoô ninu awoôn olorin asiko yii ko ti i ribeô de rara. Bo tileô jeô pe Ijeôbu-Igbo ni baba naa n gbe ju, ile ti Haruna koô s'Ekoo yii nikan, bi ko to meôwaa, yoo din dieô ni, awoôn ile nla nla si ni gbogbo woôn. Sôugboôn gbogbo eleyii koô lawoôn araalu n tori eô gbe e geôgeô, nitori orin reô ni. Orin reô yii lo; koô¯ ti; ko¯ ku;, bo tileô jeô pe oun to koôrin naa ti ku. Iyeôn ni gbogbo aye sôe n ranti reô pe Oôba ni. Ta waa ni Haruna Isôoôla yii, ta ni baba reô, bawo lo sôe dolorin, to si di Oôba. Iyeôn la o beôreô loôseô to n boô ninu AKANSôE ALAROYE, itan teôyin naa ko ni i feô ko tan ni. Oôseô to n boô la o beôreô, lagbara loôwoô Oôloôrun Oôga Ogo.

lara iyawo Babalawo Ismaila to fee bombu soosi n'Ikorodu si wa lodo awon olopaa Bolaji yii ma daju o Nise lo lu Iya to bi Mama e pa Awon elesin musulumi nile Italy tako Boko Haraamu Idagbasoke ipinle Ondo lo je ijoba mi logun, a o si ni i boju weyin-- Mimiko Idaamu Koosi Barcelona: Chelsea fiya je won tan, ni won ba gbase lowo koosi won

E tun pade wa lori ero

E wa awon iroyin wa

Information

Microsoft Word - haruna ishola

1 pages

Find more like this

Report File (DMCA)

Our content is added by our users. We aim to remove reported files within 1 working day. Please use this link to notify us:

Report this file as copyright or inappropriate

828743